Kabiyesi’s Oriki

Highly-successful Fuji legend, Wasiu Ayinde (KWAM1) congratulated, Oba Saliu Adetunji in a traditional praise poem (Oriki) as follows:

Babami Akanmu

Igba Abere ko tokoo

Igba irawo kotoshu

Okan soso osupa

Ojugba fitila lo

Adetunji omo balogun

Ebi npejo, awun nyan

Atawun atejo, eran jije

Atekirii ataja eran ikoko ni